"THE BLACKER THE BERRY THE SWEETER THE JUICE/
I SAY THE DARKER THE FLESH,THEN THE DEEPER THE ROOTS!"
TUPAC SAYS

BLACK SKINNED BEAUTY SUPREME!

BLACK SKINNED BEAUTY SUPREME!

"BLACK IS BEAUTIFUL" -NEW YORK CITY STREET SAYING

"BLACK IS BEAUTIFUL!
BROWN IS HIP,
PUERTO RICAN IS OKAY
BUT white AIN'T S___T!"

BLACK SKINNED BEAUTY OOO!

BLACK SKINNED BEAUTY OOO!

BLACK SKINNED BEAUTY OOO!

BLACK SKINNED BEAUTY OOO!

BLACK SKINNED BEAUTY SUPREME

BLACK SKINNED BEAUTY SUPREME
BLACK SKINNED BEAUTY SUPREME!

BLACK SKINNED BEAUTY SUPREME

BLACK SKINNED BEAUTY SUPREME

BLACK SKINNED BEAUTY

BLACK SKINNED BEAUTY

Search This Blog

Pages

WE MUST HAVE A BLACK STANDARD OF BEAUTY BASED ON THE BLACK SKINNED BLACKEST WOMAN

Monday, February 14, 2011

YORUBA KEYBOARD AT FACEBOOK-ABEOKUTA.ORG- LEARN YORUBA LANGUAGE-THE MOST BEAUTIFUL LANGUAGE IN THE WORLD!

http://www.facebook.com/home.php#!/apps/application.php?id=199889225883

The Yoruba Keyboard (Facebook application) makes it easy to type Yoruba dotted letters (Ọ Ṣ Ẹ) and Yoruba accent tone marks ( à ú ò) on Facebook without additional hardware special software or customized fonts installed on your Computer
Information
(5.0 out of 5)
Based on 3 reviews
5
Users:32 monthly active usersCategoryUtilities
32 monthly active users
Utilities
1 Friend Likes This                

Yoruba KeyboardYoruba Keyboard

Yoruba Keyboard Irun dídì àti kikó
- láti ọwọ́ Ajialàrà.

Irun dídì àti Kikó ní àṣà Yorùbá jẹ́ lara ohún ti máa bùkún ẹwà fùn Obìnrin wa.
Bi a ba kọ́kọ́ ri obìnrin, irun orí jẹ́ ohùn ti a o wo, bóyá o dára tàbí ko dára.
...A máa wo oríṣiríṣi irun dídì and kikó ti àtijọ́ àti ti òde ìwòyí.

http://www.abeokuta.org/yoruba/?p=2200

See More
February 7 at 6:10pm · · · Share

Yoruba Keyboard
February 3 at 5:51pm · · · Share

Yoruba Keyboard
Kíni ẹ yin ro wípé “Snow” ní èdè Gẹ̀ẹ́si, túmọ̀ si ní èdè Yorùbá?
February 2 at 2:26pm · · · Share
 • Ise Aanu likes this.
Yoruba Keyboard
January 29 at 6:42pm · · · Share
Yoruba Keyboard
January 22 at 6:21pm · · · Share
Yoruba Keyboard
Eré Ayò - o yá, ẹ jẹ ka ta ayò lórí ibùdó ayélújára yìí, ní ibí – Abẹokuta.ORG.
January 16 at 8:03pm · · · Share

Yoruba Keyboard
January 10 at 7:18am · · · Share
 • 2 people like this.
  • Ise Aanu Thanks for the encouragement and up- liftment . Great presentation too. I like the animation .More please!!
   January 10 at 2:01pm · ·
Yoruba Keyboard
Ọdún dé Ọdún Olówó Ọdún Ọlọmọ Ẹmi a sọpọ ẹ! Ẹku ọdún! Ẹku iyedún! Arọdún j’ọdún Aroṣù j’oṣù A ṣèyí samọdún A ṣeyi ṣẹmii Aṣọdún mọdún ni ṣawo Aṣọdún mọdún aṣoṣù moṣù Aṣẹ oṣù moṣù ni ṣawo aṣoṣumoṣu Gbogbo àwa ti a ri ọdún yi laṣe òmíràn ooo, Àmín! B’ọdún ba dé, a ri nkan ajọdún Ọ...

Yoruba Keyboard
Hemos notado que mucha gente ha venido a este sitio (Abeokuta.ORG) de los países de habla Española en América del Sur. Sabemos que la religión Yoruba tradicional, la Santería, es frecuente en muchos países sudamericanos. También estamos conscientes del antiguo dialecto de Yoruba Lucumí en América de

Yoruba Keyboard
Ẹ kú ọdún Kérésìmesì yìí o! Ẹ kú iyedún! Ẹ̀mí wa yíò ṣe ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ọdún láyé. A fẹ́ fi àsìkò yìí dúpẹ́ lọwọ́ gbogbo àwọn ti o wa si ibùdó ayéjúlára wa (eyìí ti àwọn òyìbó gẹ̀ẹ́sì npè ni “website”). Bákànnáà a kí gbogbo àwọn ti o kọ̀wé ni èdè Yorùbá láti fèsì si ọ̀rọ̀ ti a kọ̀ lórí ibùdó ayéjúlár...
December 24, 2010 at 11:42pm · · · Share
 • 4 people like this.
Yoruba Keyboard
December 21, 2010 at 6:37pm · · · Share
Yoruba Keyboard

Yoruba Keyboard Video Demo - Facebook Wall Status updates with Yorùbá dotted letters along with Yorùbá accent tone marks ....

December 12, 2010 at 6:04pm · · · Share

  • Bassey Ebenso Dear Yoruba Keyboard, Thank you so much for this update Re: dotted letters and tonal marks. With this one does not need an external Yoruba keyboard at all. This will be invaluable for my research!!
   December 19, 2010 at 9:35am · ·
Yoruba Keyboard
November 25, 2010 at 9:01pm · · · Share
Yoruba Keyboard

Yoruba Keyboard Another Question? If there was a phone number that you could Call into and record your Blog Comment or Contribution in Yorùbá and then on the back end we would "convert" your oral Yorùbá Blog Comment or (oral) Contribution into written Yorùbá text, would that make things easier on our Yorùbá language blog i.e. Yorùbá gbòde?

Yorùbá gbòde is a Yoruba language (blog) website with a built-in Yoruba keyboard located at www.Abeokuta.ORG. Our Yoruba language blog postings are written with standard Yoruba orthography including Yoruba tone marks, Yoruba accents marks, diacritics and under-dots. The inclusion or presence of Yoru

Yoruba Keyboard

Yoruba Keyboard Question - Do you find Reading our Yorùbá language blog (Yorùbá gbòde) too complicated?
Please let us know what we can do to make it easier for you to read and understand our Yorùbá language blog?
What do we need to Simplify on our Yorùbá language blog?
Thanks!
Yorùbá gbòde - http://www.abeokuta.org/yoruba/

November 20, 2010 at 3:15pm · ·

  • Honourable Oluwasegun sometimes,i find it difficult to understand
   November 20, 2010 at 3:27pm · ·
  • Yoruba Keyboard Thanks Olúwaṣégun for your feedback - appreciate it! How can we make Reading our Yorùbá language blog easier for you?
   November 20, 2010 at 3:34pm · ·
Yoruba Keyboard
November 13, 2010 at 5:40pm · · · Share
Yoruba Keyboard
Ìparí oṣù kẹ́wàá ní àsìkò ọdùn Halloween ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Àwọn ọmọdé máa kiri àdúgbò pẹ̀lú oríṣiríṣi ẹ̀wù ti o dẹ́rùba ènìyàn àti nǹkan miràn ti o bo ojú wọn, èyí lo mú mi rántí àwọn Egúngún ní ilẹ̀ Yorùbá. Ọ̀nà wo ní Halloween àti Egúngún fi jọra wọn? Kiní ìyàtọ̀ ti o wa làárín Halloween a...
November 1, 2010 at 5:44am · · · Share

Yoruba Keyboard

Yoruba Keyboard Quick question for Everybody?
If there was an easy way to automatically add Yorùbá tone marks or type Yorùbá dotted letters would you include them in your Yorùbá words?
For example, if there was an easy way to type house (ilé) or land (ilẹ̀) in Yorùbá, would you type those Yorùbá words that way or alternatively would you... type "ile" and let the Reader of your statement figure out if you meant house or land?
Thanks!

See More
October 31, 2010 at 3:36pm · ·
 • 2 people like this.
  • Yoruba Keyboard
   ‎1. Pátá-pátá; là ńfọ́jú, kùm̀bọ̀-kumbọ là ńdẹ́tẹ̀; ojú à-fọ́-ì-fọ́-tán ìjà ní ńdá sílẹ̀.
   One's blindness should be absolute, and one's leprosy should pervade the whole body; half-blindness only brings dissensions

   2.Má bà á loògùn ẹ̀tẹ̀.
   A...voiding contact is the only medicine for leprosy.
   (The best way out of trouble is not to get into it in the first place.)

   3. A f'ẹ̀tẹ̀ lẹ̀, a npa làpálàpá – we ignore the leprosy, and dedicate ourselves to the cure of the ringworm. ...
   See More
   November 4, 2010 at 7:16am · ·
  • Bassey Ebenso Many thanks Yoruba Keyboard for going out of your way to search for proverbs that might help expand my collection. The three suggested are already included in my collection of 20 proverbs
   November 4, 2010 at 8:43am · ·
Yoruba Keyboard
A dúpẹ́ a tọ́pé dá Àjọ̀dún wọ̀lú dé, tá a wà lómìnira. Ẹni àjọ̀dún bá dún fún lọ́nà kìínní Ẹní bá ríre tirẹ̀ nígbà òmìnira A ní ẹ wolé iṣẹ́ nlánlá A ní ẹ woṣé òwó kànkàkànkà Ẹ wo Fásitì káàkiri Ẹ tún máa wole àwòṣífìlà Tá a ti kọ sáàrin ìlú nlánlá Tijọba nfi lọ́lẹ̀ lẹ́hìn òmìnira Òmìnira...
October 23, 2010 at 8:28pm · · · Share
Yoruba Keyboard
Gbogbo ọ̀dọ́ pàtà, Ẹ kú ìbánigbáṣàa tàwa ga; Gbogbo ìpẹ́ẹ́rẹ̀ ìlú. Ẹ kúu yíyòǹbó àṣà. Àṣà ìbílẹ̀ ń fà wá, T’àjèjì náà ò jẹ́ á gbádùn. Èmi ò pé á má ṣèyí tó wù wá, Ṣùgbọń ohun t’eni ló ṣeé mú yangàn láwùjọ, Ohun a bá yá kan kì í yẹ̀’niyàn. Édè àt’àṣà wa ò ní rẹ̀yìn.
October 2, 2010 at 4:40pm · · · Share

Yoruba Keyboard
Àsìkò ni gbogbo nǹkan Mo mọyì àsìkò ní tèmi. Gbogbo ìgbésí ayé ẹ̀dá, pẹ̀lú àsìkò ni Má fàsìkò ṣeré ọ̀ré mi. Òní yẹ́, ọ̀la yẹ̀ Ọjọ ń lọ nìyẹn. Ma fàsìkò ṣeré ọ̀rẹ́ mi Ṣohun tó tọ lásìkò tó yẹ́.

Yoruba Keyboard
1. Gbé ẹsẹ̀ lé? 2. Bu ẹ̀tẹ́ lu? 3. Fa ara ya? 4. Já ewé dímú? 5. Fi ọ̀rọ̀ falẹ̀?

Yoruba Keyboard
Ìṣọ̀kan lòògùn ọ̀rẹ́, Ìyapa l’ọ̀tá ìṣọ̀kan, Ìfẹ́ nikan l’ó le ṣè ‘rẹpọ̀. Ọ́mọ aráye, ẹ jẹ́ a fara mọ́ ‘ra, Báa bá lówó ká tọ́jú mẹ̀kúnnù. Torí ikú t’ó polówó ní í powó, Báa sì nípò gidi, ká fi gb’énìyàn dókè, Torí ‘kú ó p’onípò t’òun tipòo rẹ̀, Ìṣòkàn ló ń mú ‘tẹ̀síwájú wá, Ọmọ aráyé, ẹ parapọ̀ ká d...
August 28, 2010 at 7:29pm · · · Share
Yoruba Keyboard
August 23, 2010 at 3:36am · · · Share
Yoruba Keyboard
Ní Amẹ́ríkà èdè kan wà ti wọn pè ní Spanglish. Èdè yìí jẹ́ àdàlù èdè Spanish (Español) pẹ̀lú èdè Gẹ̀ẹ́sì (English). Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn alákọ̀wé (ti wọn jẹ́ ọmọ Yorùbá) ti wọn bá sọ̀rọ̀, ẹ máa ṣe àkíyèsí pe àdàlù èdè Yorùbá pẹ̀lú Gẹ̀ẹ́sì ní wọn sọ, èyí ni a lè pè ni “Yorùbánglish”. Ẹ wo àpẹrẹ yìí láti ...
August 14, 2010 at 8:47pm · · · Share
 • 2 people like this.
Yoruba Keyboard
Gbogbo wa mọ̀ wípé òńkọ̀wé Mark Twain jẹ́ ọkan nínú àwọn òńkọ̀wé pàtàkì nínú ilẹ̀ Amẹ́ríkà, gẹ́gẹ́bí William Shakespeare ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì tàbí Bàbá D.O. Fágúnwà ní ilẹ̀ Yorùbá. Ṣugbọn púpọ̀ nínú wa ní kò mọ̀ wípé Mark Twain pa òwe Yorùbá méjì nínú ìwé ti wọ́n kọ ni ọdún 1915, èyí ti akọ́lé rẹ̀ (ni èd...
August 8, 2010 at 6:32pm · · · Share
 • 2 people like this.
Yoruba Keyboard
Àwọn ọmọ bíbí ilẹ̀ Yorùbá pọ̀ ka kiri àwọn ìpínlẹ̀ àti ìlú Amẹ́ríkà. Ko si ìlú pàtàkì ní Amerika, ti ẹ ti ní ri ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ọmọ Yorùbá, bo jẹ ìlú Atlanta (ní ìpínlẹ̀ Georgia) tàbí ìlú Houston (ní ìpínlẹ̀ Texas) tàbí ìlú nlá New York. Gẹ́gẹ́bí ẹ ti mọ̀, ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn baba-nlá àwọn ènìyàn aláw...
July 3, 2010 at 5:03pm · · · Share
Yoruba Keyboard
Ní ìparí ọ̀sẹ̀ ti o kọjá ìdíje bọ́ọ̀lù afẹsẹ̀gbá àgbáyé bẹ̀rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Gúúsù ilẹ̀ Áfíríkà. Mo ní ibéèrè nípa eré bọ́ọ̀lù afẹsẹ̀gbá? Ta ló mọ ìtúmọ̀ enití àwọn elèdè Gẹ̀ẹ́sì npè ní “Referee” ní èdè Yorùbá?
June 20, 2010 at 9:45pm · · · Share

Yoruba Keyboard
apps.facebook.com
Báwo ní a nṣe kí Ọba ní ilẹ̀ Yorùbá?
June 20, 2010 at 12:45am · · · Share
Yoruba Keyboard
Available Free of charge from iTunes - Yoruba Names iPhone App with details regarding 16,000 Yoruba Names that are individually defined and explained with the correct spellings that incorporate (phonetic) Yorùbá tonal accent marks and Yorùbá dotted letters, that are typically omitted, in documentati...
April 12, 2010 at 5:42am · · · Share

Yoruba Keyboard
Ìtọ́ka sí ìparí – Olùdásílẹ̀ Facebook ti dá ibùdó titun sílẹ lori ẹ̀rọ ayélújára pẹ̀lú orúkọ Yorùbá »
March 28, 2010 at 7:03pm · · · ShareNo comments: