Pages

Wednesday, February 24, 2016

EGUNGUN OOOO!--YORUBA OOOOO!-FROM FACEBOOK-YORUBA ART YORUBA RELIGION

FROM FACEBOOK
Egungun..... I love it !!!!!! Egun ara orun kinkin.....
1 comment
Comments
Khalid Ayanshina
Khalid Ayanshina egun ara orun kinkinSee Translation

Sikiru Adewoye Idalu ni Iselu. Eegun ni gb'owo ode Osogbo. Atokun ni gba t'Oyo.
Eegun Labala Eegun ni
Lagbanko Eegun Ode Eegun ni
Eyeba Eegun Olokiti ni
Lebe Eegun Alare ni
Ko si Eni le p'Eegun re
Awon Eleegun so wipe Ebo ko l'Eegun
Won ni Enu l'Ebo
Olubobotiri bo Baba Ebo
Eegun o le parun
Won ni gbogbo Esin ni se Eegun
Won ni Eleha n ko?
Won tun ni Aso ti a wo f'Oku
Ago Eegun Ara Orun Kinkin ni

No comments:

Post a Comment