Pages

Wednesday, November 05, 2014

OMO YORUBA! -OJO IBI MI-70TH-OCT.31ST- OMO MI E KI MI DAADAA!-NI FACEBOOK

Ara eba mi Kalo si Adeyipo ni Ilu Ibadan Lati ki IYA Mi IYA RERE, IYA DADA, IYA OLORIRE, IYA Malik, IYA Fabayo, IYA Olabisi, IYA Fehintolu, IYA Oluwasola. ABIYAMO TOTO,KU OJOBI, ASEYI SE AMODUN O, IGBA ODUN, ODUN KAN, ALAFIA ARA AMA JE YIN O, EMA JE OUNJE OMO PE, PE PE NI A GBARA OLORUN. AMIN......

No comments:

Post a Comment